Anthem | Ibadan Anthem | | Print | |
| Written by Ibadan Descendants Union USA | |
| Tuesday, 06 March 2007 | |
|
Ibadan Ilu Ori oke Ilu Ibukun Oluwa K'Oluwa se o nibukun Fun Onile at'Alejo Egbe: Eho e yo ke si gberin Ogo f'Olorun wa Io'orun Ibukun ti Obangiji Wa pelu re wo Ibadan Ibadan ilu to ngbajeji Tiko si gbagbe omo re Kife ara ko wa sibe Fun Onile at'Alejo Egbe: Eho e yo ke si gberin Ibadan, ilu Jagunjagun Awon to so o dilu nla Awa omo re ko ni je K'ola ti ogo won run Egbe: Eho e yo ke si gberin Mo wo lati ori oke Bi ewa re ti dara to B'odo re ko tile dara Sibe o Ia Ibadan ja Egbe: Eho e yo ke si gberin Ibadan ilu ori oke K'Oluwa se o nibukun Ki gbogbo Joye inu re Je elemi gigun fun wa Egbe: Eho eho ke si gberin |